Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 40:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Pèpéle kan wà níbi ẹnu ọ̀nà, tí gígùn rẹ̀ rí bákan náà pẹlu ẹnu ọ̀nà, èyí ni pèpéle tí ó wà ní ìsàlẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:18 ni o tọ