Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 40:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Yàrá mẹta mẹta wà ní ẹ̀gbẹ́ kọ̀ọ̀kan ẹnu ọ̀nà náà. Bákan náà ni ìwọ̀n àwọn yàrá mẹtẹẹta rí. Bẹ́ẹ̀ náà sì ni ìwọ̀n àtẹ́rígbà wọn, ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:10 ni o tọ