Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 39:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn oṣù meje wọn yóo yan àwọn kan tí wọn óo la ilẹ̀ náà já, tí wọn óo máa wá òkú tí ó bá kù nílẹ̀, tí wọn óo sì máa sin wọ́n kí wọ́n lè sọ ilẹ̀ náà di mímọ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 39

Wo Isikiẹli 39:14 ni o tọ