Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 39:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, fi àsọtẹ́lẹ̀ bá Gogu wí, sọ fún un pé OLUWA Ọlọrun ní: ‘Mo lòdì sí ọ́, ìwọ Gogu, ìwọ tí o jẹ́ olórí Meṣeki ati Tubali.

Ka pipe ipin Isikiẹli 39

Wo Isikiẹli 39:1 ni o tọ