Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 37:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá sọ àsọtẹ́lẹ̀ bí OLUWA ti pàṣẹ fún mi. Bí mo ti sọ àsọtẹ́lẹ̀ tán, mo bẹ̀rẹ̀ sí gbọ́ ariwo ati ìrọ́kẹ̀kẹ̀, àwọn egungun náà sì bẹ̀rẹ̀ sí so mọ́ ara wọn; egungun ń so mọ́ egungun.

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:7 ni o tọ