Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 37:3 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá bi mí léèrè, ó ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, ǹjẹ́ àwọn egungun wọnyi lè tún jí?”Mo bá dáhùn, mo ní, “OLUWA, ìwọ nìkan ni o mọ̀.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:3 ni o tọ