Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 36:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“N óo fi ìtara sọ̀rọ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè yòókù ati gbogbo Edomu, tí wọ́n fi tayọ̀tayọ̀ pẹlu ọkàn ìkórìíra sọ ilẹ̀ mi di ogún wọn, kí wọ́n lè gbà á, kí wọ́n sì pín in mọ́wọ́, nítorí wọ́n rò pé ilẹ̀ mi ti di tiwọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 36

Wo Isikiẹli 36:5 ni o tọ