Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 34:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò tọ́jú àwọn tí wọn kò lágbára, ẹ kò tọ́jú àwọn tí ń ṣàìsàn, ẹ kò tọ́jú ẹsẹ̀ àwọn tí wọn dá lẹ́sẹ̀, ẹ kò mú àwọn tí wọn ń ṣáko lọ pada wálé; ẹ kò sì wá àwọn tí wọ́n sọnù. Pẹlu ipá ati ọwọ́-líle ni ẹ fi ń ṣe àkóso wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:4 ni o tọ