Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 34:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé kí ẹ máa jẹ oko ninu pápá dáradára kò to yín ni ẹ ṣe ń fi ẹsẹ̀ tẹ àjẹkù yín mọ́lẹ̀? Ṣé kí ẹ mu ninu omi tí ó tòrò kò to yín ni ẹ ṣe fẹsẹ̀ da omi yòókù rú?

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:18 ni o tọ