Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 34:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“N óo wá àwọn tí ó sọnù, n óo sì mú àwọn tí wọ́n ṣáko lọ pada, n óo tọ́jú ọgbẹ́ àwọn tí wọ́n farapa, n óo fún àwọn tí kò lókun lágbára, ṣugbọn àwọn tí wọ́n sanra ati àwọn tí wọ́n lágbára ni n óo parun, nítorí òtítọ́ inú ni n óo fi ṣọ́ àwọn aguntan mi.

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:16 ni o tọ