Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 34:14 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún wọn ní koríko tí ó dára jẹ, orí òkè Israẹli sì ni wọn óo ti máa jẹ koríko. Níbẹ̀, ninu pápá oko tí ó dára ni wọn óo dùbúlẹ̀ sí; ninu pápá oko tútù, wọn yóo sì máa jẹ lórí àwọn òkè Israẹli.

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:14 ni o tọ