Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 34:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí olùṣọ́-aguntan tií wá àwọn aguntan rẹ̀ tí ó bá jẹ lọ, bẹ́ẹ̀ ni n óo wá àwọn aguntan mi, n óo sì yọ wọ́n kúrò ninu gbogbo ibi tí wọ́n fọ́nká sí ní ọjọ́ tí ìkùukùu bo ilẹ̀, tí òkùnkùn sì ṣú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:12 ni o tọ