Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 33:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń wá sọ́dọ̀ rẹ bí àwọn eniyan tií wá, wọ́n sì ń jókòó níwájú rẹ bí eniyan mi. Wọ́n ń gbọ́ ohun tí ò ń wí, ṣugbọn wọn kò ní ṣe é; nítorí pé ẹnu lásán ni wọ́n fi ń sọ pé wọ́n ní ìfẹ́ pupọ, ṣugbọn níbi èrè tí wọn ó jẹ ni ọkàn wọn wà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 33

Wo Isikiẹli 33:31 ni o tọ