Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 33:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, wí fún wọn pé OLUWA Ọlọrun ní, Ẹ̀ ń jẹ ẹran pẹlu ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, ẹ̀ ń bọ oriṣa, ẹ sì ń pa eniyan, ṣé ẹ rò pé ilẹ̀ náà yóo di tiyín?

Ka pipe ipin Isikiẹli 33

Wo Isikiẹli 33:25 ni o tọ