Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 33:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí eniyan burúkú bá sì yipada kúrò ninu ibi tí ó ń ṣe, tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ohun tí ó dára tí ó sì tọ́, yóo yè nítorí rere tí ó ṣe.

Ka pipe ipin Isikiẹli 33

Wo Isikiẹli 33:19 ni o tọ