Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 33:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé mo gbọ́ ohun tí wọn ń sọ pé, ‘Àìdára wa ati ẹ̀ṣẹ̀ wa wà lórí wa, a sì ń joró nítorí wọn; báwo ni a óo ṣe yè?’

Ka pipe ipin Isikiẹli 33

Wo Isikiẹli 33:10 ni o tọ