Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 32:29 BIBELI MIMỌ (BM)

“Edomu náà wà níbẹ̀ pẹlu àwọn ọba ati àwọn ìjòyè rẹ̀. Bí wọ́n ti lágbára tó, wọ́n sùn pẹlu àwọn tí wọ́n kú lójú ogun. Wọ́n sùn pẹlu àwọn aláìkọlà, pẹlu àwọn tí wọ́n ti lọ sí ipò òkú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 32

Wo Isikiẹli 32:29 ni o tọ