Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 32:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo bá sọ ilẹ̀ Ijipti di ahoro, tí mo bá pa gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ run; tí mo bá pa gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀ run, wọn yóo mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Isikiẹli 32

Wo Isikiẹli 32:15 ni o tọ