Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 31:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní: “Nígbà tí ó bá wọ isà òkú ọ̀gbun ilẹ̀ pàápàá, n óo ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, n óo sé àwọn odò n óo sì ti orísun omi ìsàlẹ̀ ilẹ̀ nítorí rẹ̀, òkùnkùn óo bo Lẹbanoni, gbogbo igi inú igbó yóo gbẹ nítorí rẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 31

Wo Isikiẹli 31:15 ni o tọ