Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 30:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tó bá tó àkókò, n óo rán àwọn ikọ̀ ninu ọkọ̀ ojú omi, wọn ó lọ dẹ́rù ba àwọn ará Etiopia tí wọn ń gbé láìfura. Wahala yóo dé bá àwọn ará Etiopia ní ọjọ́ ìparun Ijipti. Wò ó, ìparun náà ti dé tán.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 30

Wo Isikiẹli 30:9 ni o tọ