Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 30:26 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fọ́n àwọn ará Ijipti ká sáàrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, n óo sì tú wọn káàkiri gbogbo ilẹ̀ ayé. Wọn óo sì mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 30

Wo Isikiẹli 30:26 ni o tọ