Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 30:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo lòdì sí Farao, ọba Ijipti. Èmi OLUWA Ọlọrun ní mo sọ bẹ́ẹ̀. N óo ṣẹ́ ẹ ní apá mejeeji: ati èyí tó ṣì lágbára, ati èyí tí ó ti ṣẹ́ tẹ́lẹ̀; n óo sì gbọn idà bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 30

Wo Isikiẹli 30:22 ni o tọ