Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 30:12 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo mú kí odò Naili gbẹ, n óo ta ilẹ̀ náà fún àwọn eniyan burúkú; n óo sì jẹ́ kí àwọn àjèjì sọ ilẹ̀ náà ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ di ahoro. Èmi OLUWA ní mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 30

Wo Isikiẹli 30:12 ni o tọ