Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí òkúta adamanti ṣe le ju òkúta akọ lọ ni mo ṣe mú kí orí rẹ le ju orí wọn lọ. Má bẹ̀rù, má sì ṣe jẹ́ kí ojú wọn já ọ láyà, nítorí pé ìdílé ọlọ̀tẹ̀ ni wọ́n.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 3

Wo Isikiẹli 3:9 ni o tọ