Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí o bá kìlọ̀ fún eniyan burúkú, tí kò bá yipada kúrò ninu iṣẹ́ burúkú tí ó ń ṣe, tabi ọ̀nà ibi tí ó ń tọ̀; yóo kú sinu ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, ṣugbọn ìwọ óo gba ara rẹ là.

Ka pipe ipin Isikiẹli 3

Wo Isikiẹli 3:19 ni o tọ