Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 29:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní ọjọ́ náà, n óo gbé alágbára kan dìde ní Israẹli, n óo mú kí ìwọ Isikiẹli ó sọ̀rọ̀ láàrin wọn. Nígbà náà, wọn yóo mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 29

Wo Isikiẹli 29:21 ni o tọ