Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 29:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, Nebukadinesari ọba Babiloni mú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti ìlú Tire kíkankíkan. Wọ́n ru ẹrù títí orí gbogbo wọn pá, èjìká gbogbo wọn sì di egbò. Sibẹ òun ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ kò rí èrè kankan gbà ninu gbogbo wahala tí wọ́n ṣe ní Tire.

Ka pipe ipin Isikiẹli 29

Wo Isikiẹli 29:18 ni o tọ