Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 28:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ọpọlọpọ òwò tí ó ń ṣe, o bẹ̀rẹ̀ sí hu ìwà jàgídíjàgan, o sì dẹ́ṣẹ̀, nítorí náà mo lé ọ jáde bí ohun ìríra kúrò lórí òkè Ọlọrun. Kerubu tí ń ṣọ́ ọ sì lé ọ jáde kúrò láàrin àwọn òkúta olówó iyebíye tí ń tàn yinrinyinrin.

Ka pipe ipin Isikiẹli 28

Wo Isikiẹli 28:16 ni o tọ