Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 28:13 BIBELI MIMỌ (BM)

O wà ninu Edẹni, ọgbà Ọlọrun. Gbogbo òkúta olówó iyebíye ni wọ́n fi ṣe ọ́ lọ́ṣọ̀ọ́, àwọn òkúta bíi: kaneliani, topasi, ati jasiperi; kirisolite, bẹrili, ati onikisi; safire, kabọnku ati emeradi. A gbé ọ ka inú àwọn nǹkan ọ̀ṣọ́ wúrà tí a ṣe fún ọ ní ọjọ́ tí a dá ọ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 28

Wo Isikiẹli 28:13 ni o tọ