Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 27:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń kó ojúlówó ẹ̀wù aṣọ aláwọ̀ aró wá tà fún ọ, ati aṣọ tí wọ́n ṣe iṣẹ́ ọnà sí lára, ati ẹni tí ó ní oríṣìíríṣìí àwọ̀, tí wọ́n fi ìko hun.

Ka pipe ipin Isikiẹli 27

Wo Isikiẹli 27:24 ni o tọ