Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 26:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, nítorí pé àwọn ará ìlú Tire ń yọ̀ sí ìṣubú ìlú Jerusalẹmu, wọ́n ń sọ wí pé ìlẹ̀kùn ibodè àwọn eniyan yìí ti já, ibodè wọn sì ti ṣí sílẹ̀ fún wa, nisinsinyii tí ó di àlàpà, a óo ní àníkún.

Ka pipe ipin Isikiẹli 26

Wo Isikiẹli 26:2 ni o tọ