Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 26:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo fi pátákò ẹsẹ̀ àwọn ẹṣin rẹ̀ tú gbogbo ilẹ̀ ìgboro rẹ, yóo fi idà pa àwọn eniyan rẹ; yóo sì wó àwọn òpó ńláńlá rẹ lulẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 26

Wo Isikiẹli 26:11 ni o tọ