Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 24:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní: “Ègbé ni fún ìlú apànìyàn, ìkòkò tí inú rẹ̀ dípẹtà, tí ìdọ̀tí rẹ̀ kò ṣí kúrò ninu rẹ̀! Yọ ẹran inú rẹ̀ kúrò lọ́kọ̀ọ̀kan, sá máa mú èyí tí ọwọ́ rẹ bá ti bà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 24

Wo Isikiẹli 24:6 ni o tọ