Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 24:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ẹ gbé òfìfo ìkòkò náà léná, kí ó gbóná, kí idẹ inú rẹ̀ lè yọ́; kí ìdọ̀tí tí ó wà ninu rẹ̀ lè jóná, kí ìpẹtà rẹ̀ sì lè jóná pẹlu.

Ka pipe ipin Isikiẹli 24

Wo Isikiẹli 24:11 ni o tọ