Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:47 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ogunlọ́gọ̀ eniyan wọnyi óo sọ wọ́n lókùúta, wọn óo sì gún wọn ní idà. Wọn óo pa àwọn ọmọ wọn; tọkunrin tobinrin, wọn óo sì dáná sun ilé wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:47 ni o tọ