Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn olódodo eniyan ni yóo dá àwọn obinrin náà lẹ́jọ́ panṣaga, ati ti apànìyàn, nítorí pé panṣaga eniyan ni wọ́n, wọ́n sì ti paniyan.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:45 ni o tọ