Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:40 BIBELI MIMỌ (BM)

“Wọ́n tilẹ̀ tún ranṣẹ lọ pe àwọn ọkunrin wá láti òkèèrè, oníṣẹ́ ni wọ́n gbé dìde kí ó lọ pè wọ́n wá; àwọn náà sì wá. Nígbà tí wọ́n dé, ẹ wẹ̀, ẹ kun àtíkè, ẹ tọ́ ojú, ẹ sì ṣe ara yín lọ́ṣọ̀ọ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:40 ni o tọ