Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe fi òpin sí ìṣekúṣe ati àgbèrè tí o kó ti ilẹ̀ Ijipti wá. O kò ní ṣíjú wo àwọn ará Ijipti mọ́, o kò sì ní ranti wọn mọ́.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:27 ni o tọ