Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:21 BIBELI MIMỌ (BM)

O tún fẹ́ láti máa ṣe ìṣekúṣe tí o ṣe nígbà èwe rẹ, tí àwọn ọkunrin Ijipti ń dì mọ́ ọ lẹ́gbẹ̀ẹ́, tí wọ́n sì ń fi ọwọ́ fún ọ ní ọmú ọmọge.

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:21 ni o tọ