Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń ṣẹ́jú sí àwọn ará Asiria: àwọn gomina ati àwọn ọ̀gágun, àwọn ọmọ ogun tí wọ́n di ihamọra, tí wọn ń gun ẹṣin, ọdọmọkunrin ni gbogbo wọn, ojú wọn fanimọ́ra.

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:12 ni o tọ