Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 21:28 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé ohun tí èmi OLUWA Ọlọrun sọ nípa àwọn ará Amoni ati ẹ̀gàn wọn nìyí:‘A ti fa idà yọ, láti paniyan.A ti fi epo pa á kí ó lè máa dán, kí ó sì máa kọ mànà bíi mànàmáná.

Ka pipe ipin Isikiẹli 21

Wo Isikiẹli 21:28 ni o tọ