Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 21:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ṣí fìlà, kí ẹ sì ṣí adé ọba kúrò lórí, gbogbo nǹkan kò ní wà bí wọ́n ṣe rí. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀. Ẹ gbé àwọn tí ipò wọn rẹlẹ̀ ga, kí ẹ sì rẹ àwọn tí ipò wọn wà lókè sílẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 21

Wo Isikiẹli 21:26 ni o tọ