Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 20:38 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo ṣa àwọn ọlọ̀tẹ̀ ati àwọn tí ń ṣe oríkunkun sí mi kúrò láàrin yín. N óo mú wọn kúrò ní ilẹ̀ tí wọ́n ti jẹ́ àlejò, ṣugbọn wọn kò ní dé ilẹ̀ Israẹli. Ẹ óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 20

Wo Isikiẹli 20:38 ni o tọ