Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan sọ fún àwọn àgbààgbà Israẹli pé, OLUWA Ọlọrun ní, ‘Ṣé ẹ wá wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ mi ni? Mo fi ara mi búra pé, n kò ní da yín lóhùn. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.’

Ka pipe ipin Isikiẹli 20

Wo Isikiẹli 20:3 ni o tọ