Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 20:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, mo fún wọn ní ọjọ́ ìsinmi, kí ó máa jẹ́ àmì láàrin èmi pẹlu wọn, kí wọ́n lè mọ̀ pé èmi OLUWA yà wọ́n sí mímọ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 20

Wo Isikiẹli 20:12 ni o tọ