Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 19:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ ìwọ̀ sí i nímú,wọ́n gbé e jù sinu àhámọ́,wọ́n sì fà á lọ sí ọ̀dọ̀ ọba Babiloni.Wọ́n fi sí àtìmọ́lé,kí wọ́n má baà gbọ́ ohùn rẹ̀ mọ́ lórí àwọn òkè Israẹli.

Ka pipe ipin Isikiẹli 19

Wo Isikiẹli 19:9 ni o tọ