Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Iná ṣẹ́ lára igi rẹ̀,ó sì jó gbogbo ẹ̀ka ati èso rẹ̀.Kò sì ní igi tí ó lágbára mọ́,tí a lè fi gbẹ́ ọ̀pá àṣẹ fún ọba.Dájúdájú ọ̀rọ̀ arò ni ọ̀rọ̀ yìí, ó sì ti di orin arò.

Ka pipe ipin Isikiẹli 19

Wo Isikiẹli 19:14 ni o tọ