Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ka rẹ̀ tí ó lágbárani a fi gbẹ́ ọ̀pá àṣẹ fún àwọn olórí.Ó dàgbà, ó ga fíofío, láàrin àwọn igi igbó.Ó rí i bí ó ti ga, tí ẹ̀ka rẹ̀ sì pọ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 19

Wo Isikiẹli 19:11 ni o tọ