Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 19:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA ní kí n sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn nítorí àwọn olórí Israẹli,

2. kí n sọ pé:Abo kinniun pataki ni ìyá rẹ láàrin àwọn kinniun!Ó dùbúlẹ̀ láàrin àwọn ọ̀dọ́ kinniun,ó ń tọ́jú àwọn ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 19