Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

tí ó ń rìn ninu ìlànà mi, tí ó sì ń fi tọkàntọkàn pa òfin mi mọ́, olódodo ni irú ẹni bẹ́ẹ̀, yóo sì yè. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:9 ni o tọ